AMINU AHMED TO N FORUKO OSISE ATIKU LU JIBITI TI JEWO O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, November 10, 2018

AMINU AHMED TO N FORUKO OSISE ATIKU LU JIBITI TI JEWO O

Owo olopaa ti te Aminu Ahmed Yerima ti won lo n foruko adije sipo Aare orileede yi lodun 2019, Atiku Abubbakar lu jibiti lori eka ayelujara, iyen Facebook lara awon to lu ni jibiti ni won loo foro e to awon olopaa leti, ki won to topinpin lati rowo to o.



Omo bibi ijoba ibile Jada niluu Adamawa ni Yerima, eeyan ti ko din ni aadota la gbo pe o ti lu ni jibiti owo ati dukia.

PÍN-IN KÁÀKIRI