GARBA LU ORE E PA NITORI IBINU LASAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, November 8, 2018

GARBA LU ORE E PA NITORI IBINU LASAN

Bi e se n ka iroyin yi, ogba olopaa nopinle Niger ni odomokunrin odaran kan ti won loo lu ore e pa nitori tiyen mu  inu bii.Ojo Tusde ana la gbo pe odaran naa, Garba Maru labule Kokani, Ogba Fulani, New Bussa nijoba ibile Borgu ti lu ore e naa Umar Mohammed pa.

PÍN-IN KÁÀKIRI