OYEGBADE OLOWOGBOYEGA DI ADELE AKOWE FUNJOBA IPINLE OSUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, November 17, 2018

OYEGBADE OLOWOGBOYEGA DI ADELE AKOWE FUNJOBA IPINLE OSUN

Bi e se n ka iroyin yi, to ku ojo mokanla tijoba Gomina Aregbesola yoo kogba wole l'Osun, gomina ti fowo si yiyan olori awon osise ijoba nipinle Osun, Dokita Oyegbade Olowogboyega gege bii adele akowe funjoba.

 
Olowogboyega ni won mu lati ropo Senato Mudashiru Hussein eni to ti di komisanna fun ajo eleto ikaniyan lorileede yii, NPC bayii.

PÍN-IN KÁÀKIRI