FEMI ADEBAYO GBE FOTO IGBA TO SI N TIRAKA JADE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, November 17, 2018

FEMI ADEBAYO GBE FOTO IGBA TO SI N TIRAKA JADE

Foto ti gbajumo osere tiata nni, Femi Adebayo gbe sori eka ayelujara lojo Tosde ijeta lawon eeyan si n soro e titi dasiko yii.

Kii se pe Femi Adebayo gbe foto naa sita nikan, o tun fi gba awon eeyan lamonran pe ko si beeyan se le jiya to laye, o si maa sori-ire lojo kan.

PÍN-IN KÁÀKIRI