WON TI SINKU MAMA IBRAHIM CHATTA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, November 2, 2018

WON TI SINKU MAMA IBRAHIM CHATTA

Pẹlu ibanuje okan ni gbajumo osere tiata nni, Ibrahim Chatta fi kede sita latari bi won se sinkú mama to bíi lomo lai pe yìí nilana musulumi.


Orí eka ayelujara, Instagram ni Ibrahim ti koko kede iku mama e, tawon eeyan si bere síi kíi ku amumora.

Ko pe to tun fi kede pe awon ti sinkú mama naa. Bo tile je pe opo awon elegbe nìdí isẹ tiata to yan láàyò lo ti n ki latigba ti won ti gbo, sugbon tá a gbo pe diẹ láwọn to yoju sibi ìsìnkú náà.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI