Gomina ipinle Osun, Gboyega Oyetola ti kede Ogbeni Adeniyi Francis Adesina gege bi akowe agba feto iroyin fun sa a isejoba e.
Gege bi iroyin to te AWÍKONKO lowo se so, ana ni Gomina Gboyega Oyetola kede Ogbeni Francis Adesina gege bii akowe iroyin e niwaju awọn osise e niluu Osogbo.
AWIKONKO gbo pe igbakeji olootu agba fun iwe iroyin The Nation ni Ogbeni Adesina ti won lomo bibi ilu Ilesa ni ti sise ki Gomina Oyetola to o yan an.
No comments:
Post a Comment