AJỌ INEC GBE ORUKỌ AWỌN OLUDIJE SIPO AARE JADE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 17, 2019

AJỌ INEC GBE ORUKỌ AWỌN OLUDIJE SIPO AARE JADE

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, ajọ eleto idibo ti gbe orukọ awọn adije si gbogbo ipo oṣelu lorileede yi jade sita. Onii ni Ajọ naa, fi awọn orukọ naa sita fawọn ọmọ orileede yi lati mọ ẹni ti wọn too dibo fun un.

Image result for inec chairman

Awọn orukọ naa jẹ orukọ awọn adije sipo Aarẹ, Sẹnetọ ati aṣoju-ṣofin lorileede yi.

Awọn orukọ naa niwọnyii

AWỌN ADIJE SI IPO AARẸ

AWỌN ADIJE SIPO SẸNETỌ

AWỌN ADIJE SIPO AṢOJU-ṢOFINNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI