Ẹ WO RICHARD MOFẸ DAMIJO ATI IYAWO Ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, January 27, 2019

Ẹ WO RICHARD MOFẸ DAMIJO ATI IYAWO Ẹ

O maa n dara ki ọkunrin maa mọ riri iyawo ẹ, bẹẹ naa lo dara ki obinrin maa fi ifẹ han si ọkọ, paapaa niru asiko bi ojọ ibi.


Wọn yii gan an lọrọ to lọ nibamu pẹlu bi gbajumọ oṣere tiata oloyinbo nni, Richard Mofẹ Damijo ṣe fi imọriri han si iyawo, Arabinrin Jumọbi Abikẹ Damijo fun ti ayẹyẹ ọjọ ibi ati ayẹyẹ ọdun mejilelogun ti wọn ti jọ n gbe gẹgẹ bi ọkọ ati aya.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI