BUHARI TI BORI NIPINLẸ OGUN, IJỌBA IBILẸ MẸRINLA LO FI LA ATIKU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 25, 2019

BUHARI TI BORI NIPINLẸ OGUN, IJỌBA IBILẸ MẸRINLA LO FI LA ATIKU

Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta 

Aarẹ orileede Naijiria, Ọgagun Muhammadu Buhari ti bori idibo Aarẹ ti wọn ṣe nipinle Ogun pẹlu bo ṣe mu ijọba ibilẹ mẹrinla ninu ijọba ibilẹ ogun to wa nipinlẹ naa.

Ohun ta a gbọ ni pe ijọba ibilẹ mẹfa pere ni Alaaji Atiku Abubakar fi bori Aarẹ Buhari. Bi esi ibo naa ṣe lọ ni yii.

IJEBU-ODE LG
APC – 12,850
PDP - 7,253

IJEBU NORTH EAST LG
APC - 6,435
PDP - 5,149

REMO NORTH LG
APC - 5,659
PDP - 6,269

ODEDA LG
APC - 10,049
PDP - 4,995

ABEOKUTA NORTH LG
APC - 22,044
PDP - 7,528

SAGAMU LG
APC – 20,875
PDP - 16,532

IMEKO-AFON LG
APC - 6,425
PDP - 6,689

OGUN WATERSIDE LG
APC - 6,889
PDP - 8,262

EGBADO SOUTH LG
APC - 12,934
PDP - 10,709

OBAFEMI OWODE LG
APC - 16,243
PDP - 7,938

IKENNE LG
APC - 10,283
PDP - 8,708

ABEOKUTA SOUTH LG
APC - 26,462
PDP - 13,853

ADO ODO/OTA LG
APC - 33,348
PDP - 20,352

EWEKORO LG
APC - 10,060
PDP - 5,101

IFO LG
APC - 23,895
PDP - 8,968

IJEBU NORTH LG
APC – 13,974
PDP -16,196

ODOGBOLU LG
APC – 10,130
PDP – 10,137

IPOKIA
APC – 14,686
PDP – 12,313

YEWA NORTH
APC – 10,434
PDP – 10,388

IJEBU EAST
APC – 7,287
PDP – 7,315

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI