Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta
Ọrọ iyawo tuntun ti ọkan lara awọn
gbajumọ agbaboolu orileede Spain, to tun jẹ balogun fun ẹgbẹ agbabọọlu Real
Madrid, Sergio Ramos ṣẹṣẹ fe lawọn eeyan tun mu sẹnu lasiko yi.
Gbajumọ sọrọsọrọ ori tẹlifiṣan ni
iyawo tuntun naa, Pilar Rubio. Ọdun to kọja la gbọ pe awọn mejeeji pade, ṣugbọ
ni bayii, awọn mejueeji ti mu ọjọ igbeyawo sọna, ọjọ kẹẹdogun oṣu kẹfa ni yoo
waye ni Seville.
No comments:
Post a Comment