PASUMA, DAVIDO, JIMMY JAT ATI GUCCIMANEKO GBE RẸKỌỌDU TUNTUN JADE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, February 5, 2019

PASUMA, DAVIDO, JIMMY JAT ATI GUCCIMANEKO GBE RẸKỌỌDU TUNTUN JADE

Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta 
 
Ko si orin meji tawọn eeyan tun n sọrọ nipa lasiko yi bi ko ṣe orin tuntun ti ọkan lara awọn ti Ọlọrun fi iṣẹ orin ran, Guccimaneko ṣẹṣẹ gbe jade sita, eyi to pe ni ‘No Case’.

Guccimaneko No Case
Kii ṣe bi orin naa ṣe jade nikan lo jẹ kawọn eeyan maa sọrọ nipa ẹ, bi ko ṣe awọn ogbontarigi onkọrin takasufe to fi mọ gbajumọ olorin Fuji nni, Alaaji Wasiu Alabi Pasuma tun ṣe kopa ninu ẹ.

Lara awọn to tun wa ninu orin naa ni Davido ati DJ Jimmy Jatt.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI