Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta
Ohun ta a gbọ ni pe abule Ṣowọ nitosi Interchange ni ijamba buruku naa ti ṣẹlẹ.Wọn ni mọto tipa ti ẹ n wo yi lo da wahala naa silẹ lasiko to fẹẹ yi pada lori ere, to mu ki awọn mẹta padanu ẹmi wọn, tawọn mejila si farapa kọja afẹnusọ
No comments:
Post a Comment