IṢẸ LOOGUN IṢẸ: Ẹ WO ỌMỌBINRIN TO N GẸRUN NILUU EKO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, February 2, 2019

IṢẸ LOOGUN IṢẸ: Ẹ WO ỌMỌBINRIN TO N GẸRUN NILUU EKO

Nigerian female barber


Anita Charles lorukọ ọdọmọbinrin yi, to jẹ akẹkọọgboye nileewe Yunifasiti. Gẹgẹ bi Anita Charles ṣe sọ lori ẹrọ ayelujara twitter laipẹ yi, o loun nifẹ si lati maa ṣe irun lọṣọ, paapaa iru awọn ọkunrin


Nigerian female barber

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI