IBO 2019: ORI KO ỌṢINBAJO YỌ NINU IJAMBA ỌKỌ OFURUFU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, February 2, 2019

IBO 2019: ORI KO ỌṢINBAJO YỌ NINU IJAMBA ỌKỌ OFURUFU

Bi kii ba a ṣe pe Ọlọrun ṣi wa lẹyin igbakeji Aare orileede yi, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo ni, boya oni ni ki ba ri aye mọ latari ba a ṣe gbọ pe diẹ lo ku ko padanu ẹmi ẹ sinu ijamba ọkọ baalu kekere, iyẹn Chopper to sṣẹlẹ niluu Kabba nipinlẹ Kogi lọsan onii.

Image result for osinbajo in accident 

AWIKONKO gbọ pe ipolongo ibo saa keji Aarẹ Buhari atigbakeji rẹ ni wọn lo ba lọ sipinlẹ Kogi ko to di pe baalu kekere ọhun yọwọ lasiko to fẹẹ ba silẹ.

Ṣugbọn, gẹgẹ bi agbenusọ fun Ọṣinbajo, Ọgbẹni Laolu Akande ṣe sọ, ko si ẹnikẹni to farapa ninu ijamba naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI