Pupọ ninu awọn to ri Aarẹ orileede Naijiria, Ọgagun Muhammadu Buhari nibi to ti n gbadura kikan-kikan ni wọn mọ pe ọkan ẹ ko balẹ mọ latari idibo to fẹẹ waye lonii Satide.
Ni nnkan bi aago kan aabọ ọsan ọjọ Fraide ana ni Aarẹ Buhari atawọn alatilẹyin ẹ gba Mọṣalaṣi agba ni Daura lọ lati lọọ gbadura fun aṣeyọri ẹ ninu idibo naa.
No comments:
Post a Comment