ỌṢINBAJO FUN BABA SUWE NI MILIỌNU KAN NAIRA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, February 21, 2019

ỌṢINBAJO FUN BABA SUWE NI MILIỌNU KAN NAIRA

Igbakeji Aarẹ orileede yi, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo ti ṣe iranwọ owo oni miliọnu kan naira fun gbajumọ oṣere alawada nni, Babatunde Omidina tawọn eeyan tun mọ si Baba Suwe lati fi tọju ara ẹ ti ko ya.
Ọjọgbọn Ọṣinbajo lo gbe owo naa kalẹ labẹ ọfiisi awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Eko Ọgbẹni Arẹgbẹ Idris jẹ adari wọn.

Gbajumọ oṣere tiata nni, Rẹmi Surutu atawọn oṣere min in la gbọ pe wọn lewaju Arẹgbẹ lọ sile Baba Suwe

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI