EYI NI BI WỌN YOO ṢE SINKU ṢUGAR - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, March 18, 2019

EYI NI BI WỌN YOO ṢE SINKU ṢUGAR

Awọn mọlẹbi oloogbe nni, Temitọpẹ Ọlatoye tọpọ awọn eeyan mọ si Ṣugar ti sọ pe ọjọ keji, oṣu karun ọdun yi ni wọn yoo sinku ẹ.

Gẹgẹ bi aburo oloogbe naa, Dọtun Ọlatoye ṣe ṣalaye fawọn oniroyin laipẹ yi, o sọ pe dandan ni kawọn sinku eeyan wọn, bo tilẹ jẹ pe ibanujẹ ṣi ni iku ẹ jẹ fawọn.

Bẹ o ba gbagbe, ninu idibo to kọja lọ ni wọn ti yinbon fun aṣoju-ṣofin agbegbe Lagelu si Akinyẹle.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI