ABIỌDUN JI MỌTO L’EKO, LO BA TA SORILEEDE BẸNIN, ỌWỌ FIJILANTE TI TẸ Ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, March 16, 2019

ABIỌDUN JI MỌTO L’EKO, LO BA TA SORILEEDE BẸNIN, ỌWỌ FIJILANTE TI TẸ Ẹ


Boroboro lawn ọrẹ meji kan ti wn ko niṣẹ meji ju ole jija l n ka bayii nigba tọwọ awn fijilante, iyẹn VSO t wn lọjọ Tuside ọsẹ to lọ lọhun lagbegbe Owode Yewa, ipinl Ogun.

Akorede Surajudeen, ni gbn dun ati Abidun Adelakun, ọmọdun mkandinlgbn la gb pe ọwọ t, nigba ti wn si n ewadi nikan ti wn pe oruk ni Bde, ni ti wn loun lo ra mto naa ni Bnin.

Ohun ta a gb pe o akoba fun wn ni mto jiipu GL 4MATIC ti wn lọọ ji gbe niluu Ajah, iyn l’Eko lọjọ krinla ou keji to kọja yi, ti wn si l ta a danu lẹsẹkẹsẹ sorileede Bnin, iyn Kutnu.

Nigba tairi maa tu, ga awn fijilante tipinl Ogun, VSO, gbni Sji Ganzallo ni wn loo fọrọ naa to leti pe ko ba wn wa n kan e si, oun lo si ta gbogbo awn oṣiṣẹ ẹ lolobo pe ki wn bẹrẹ iṣẹ iwadii ni kiakia.

AWIKONKO gb ni pe lsks ti olobo ti ta wn la gb pe wn ti bẹrẹ iwadii, ko da a tawn oṣiṣẹ wn lagbegbe Idiroko to sunmo Bnin naa ti bẹrẹ iwadii. AWIKONKO gb pe ọjọ Tuside ọsẹ to kja lairi awn daran naa tu ni nnkan bi aago mfa kja iṣẹju mẹẹdogun.

Nigba to n fidi iṣẹlẹ naa mul, alukoro gb fijilante nipinl Ogun, gbni Mruf Yusuf s pe lsks tw ti t awn daran ni wn ti ka gbogbo iwa buruku ọwọ wn lai kii e pe awn dana iya fun wn.

gbni Mruf s pe awn eeyan naa jw pe ẹnikan to jẹ Bde to maa n gba ru tawn ba ji gbe lawn ta a fun ni Bnin, ati pe ninu milinu meji aab owo Bnin, iyẹn cefa, milinu kan ataab (1.400.000cefa) lawn i gba lọwọ ẹ.

O wa j ko ye wa pe ga awn, Sji Ganzallo ti paṣẹ pe kawn ko awn daran naa l sọdọ awn ọlọpaa Idiroko lati tsiwaju iwadii. Gbogbo akitiyan lati gb tnu alukoro ọlọpaa ipinl Ogun, Abimbla Oyeymi lo ja si pabo titi dasiko ta a k iroyin yi tan.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI