NITORI SẸNETỌ ADEMỌLA ADELEKE, WỌN PA TITI RẸ L'ỌṢUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, March 22, 2019

NITORI SẸNETỌ ADEMỌLA ADELEKE, WỌN PA TITI RẸ L'ỌṢUN

Ni kete ti iroyin ti jade sita pe ile ẹjọ Tribunal niluu Abuja to da adije sipo Gomina ipinlẹ Ọṣun labẹ asia ẹgbẹ oṣelu PDP, Sẹnetọ Ademọla Adeleke lọdun 2018 lare pe oun lo yege, kii ṣe Adegboyega Oyetọla lawọn alatilẹyin Adeleke ti jade sita lopo yanturu.

Kaakiri ilu Ẹdẹ, Oṣogbo lawọn araalu ti wọn fẹ ti Adeleke ti dana ariya, ti wọn si pa gbogbo opopona rẹ pelu idunnu.




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI