WỌN NI ẸGBẸ AGBABỌỌLU ARSENAL N GBARADI FUN IYA ẸLẸẸKẸTA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, April 29, 2019

WỌN NI ẸGBẸ AGBABỌỌLU ARSENAL N GBARADI FUN IYA ẸLẸẸKẸTA

Ìgbà kẹta rèé léra wọn ti ìyà ń ba ìyà fún ìkọ ẹgbẹ́ àgbabọọlu Arsenal, èyí sì mú wọn to sẹ̀yìn Chelsea ti yóò koju Manchester United ní old Trafford

Nínú ìfẹsẹwọnsẹ tó tún wáyé lónìí láàrin Leicester City àti Arsenal ní wọn ti gbẹwuro àmi àyó mẹ́ta si òdo fún Arsenal.

Ìgbáju ìgbámú ni Leiscester city ǹko fún Arsenal, eyí ti ó si ń ṣe ọkàn láàrẹ pe sé ìrètí Arsenal ó ti ré bọ sinu omi báyìí?

Kó dáju mọ báyìí bọ́ya Arsenal yóò kógojá fún Champions League.

Ibéèrè ti ó ń wáye fún Unai Emery ni pé níbo ni Arsenal ń lọ niniúdíje Champions League yìí

Ẹ̀ẹ̀mèji ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni Jamie Vardy Gbá bọ́ọ̀l sáwọn láti gbọn búrẹdi Arsenal jábọ kúrò nínú àwọn ti yóò kopa nínú ìdíje Champions League.

Bíi wákati kan gbáko ni Arsenal fui n dàmú lóri pápá lái kó èrè oko déle, bí wọn ṣe ràn Ainsley Maitland niṣẹ́ láti ló gbá èwé jọkó jẹ́jẹ́ wá.

Bótilẹ jẹ je Arsenal si ni ànfàni láti pari si ipò keeje bi ìdílje ṣe ku méji sẹyi, èyi lé mu wọn kóju òsùwọn

láti kopa ninu Europa League, wọn ni àmi àyo márun ti wọn fi n toò sẹ́yin Wolves

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI