AGBA OLOṢELU TO N FOOGUN B’AWỌN ỌMỌ KEKEEKE LAṢEPỌ L’ABẸOKUTA TI DERO ẸWỌN O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, May 10, 2019

AGBA OLOṢELU TO N FOOGUN B’AWỌN ỌMỌ KEKEEKE LAṢEPỌ L’ABẸOKUTA TI DERO ẸWỌN O

Fun bi ọpọlọpọ wakati ni mọto ko fi raaye kọja lopopona ile ẹjọ Majisireeti to fikalẹ sagbegbe Iṣabọ niluu Abẹokuta laarọ ana, ti i ṣe Fraide nigba ti ileeṣẹ ọlọpaa, ti Zonal Intervention Squared (ZIS) foju baba agba radarada kan, Ọgbẹni Peter Ọdẹjimi to sọ pe agba oloṣelu loun, ẹni ti wọn lo n foogun bawọn ọmọ kekeeke tọjọ ori wọn ko ju ọdun mẹtala lọ laṣepọ.

Lọsẹ to kọja lọ yi la gbọ pe aṣiri Peter Ọdẹjimi to ni agba oloṣelu nijọba ibilẹ ọdeda loun tu si AWIKONKO lọwọ, ta a si fa a le awọn ọlọpaa ZIS ti agbegbe Ọbada lọwọ pẹlu awọn aridaju fidio ti ko din ni mejila, nibi ti baba naa ti n bawọn ọmọ kekeeke yi laṣepọ.

Ko sibi ti iroyin Peter, ti wọn tun n pe ni Ọmọ Ọdẹ ko tan de niluu Abẹokuta ati agbegbe ẹ, to mu kawọn eeyan maa ṣepe nla-nla fun un. Ko si nnkan meji to mu ero pe jọ si kọọtu lọjọ Fraide ana, bi ko ṣe igba tiroyin kan pe yoo foju bale ẹjọ naa, ti wọn si fẹẹ wo oju ọdaran naa.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, pẹlu awọn fidio naa, kii ṣe awọn ọmọ kekeeke nikan ni Peter to n gbe lagbegbe Itẹsi mọ Ake n ba laṣepọ, o tun n bawọn iyawo ile sun, to fi mọ ọmọ to bi ninu ara rẹ sun.

Bakan naa lo tun n ba awọn ọmọ aburo rẹ tọjọ ori wọn ko ju ọdun mọkandinlogun sun. Bẹẹ la tun gbọ pe ọkan lara awọn ọmọ Peter to n jẹ Bamidele naa tun bimọ fun, tọmọ naa si ti n lọ pe ọdun mẹta bayii.

Lara awọn to fiṣẹlẹ naa to wa leti jẹ ko ye wa pe irẹsi ni Ọmọ Ọdẹ maa fi oogun sinu ẹ, ko too gbe e fawọn to ba fẹẹ ba sun lati lọọ jẹ ẹ, tawọn yẹn yoo si pada wa lati gba kinni abẹ ẹ sara.

Ọgbẹni Jamiu Arẹmu ti Peter n ba meji ninu awọn ọmọ ẹ sun naa ṣalaye baṣiri ṣe tu soun lọwọ, ati pe oun ko tete mọ afigba ti wọn fi fidio awọn ọmọ oun nibi ti baba yi ti n ko ibasun fun wọn lọwọ han oun loun too mọ.

Jamiu ṣalaye pe awọn ọmọ oun tọjọ ori wọn ko ju ọdun mẹjọ si mọkanla lawọn ọmọ oun mejeeji naa. O wa rawọ ẹbẹ pe kijọba gba oun nitori pe o ti ba aye awọn ọmọ oun jẹ kọja afẹnusọ.

Peter tọjọ ori ẹ din diẹ laadọrin (66-68years) ọdun nigba to n b’AWIKONKO sọrọ lẹyin taṣiri ẹ tu sọ pe “Kani mo mọ pe ẹnikan n ya fọnran mi ni, mi o ba ti na papa bora nitori pe mi o lero wi pe awọn eeyan n ṣọ mi ladugbo.

Iṣẹ agb ni mo n e, bẹẹ ni mo tun n e oelu, emi ni organizing secretary gb oelu APC nijba ibil deda. Mo ti le lgta dun. Gg bi awn fidio ti mo wo yi, mi o le s pe irọ ni wọn pa mọ mi, mi o si le so pe ko ri bẹẹ, tori pe ri aridaju to oju aara ni. ugbn sib, kii e pe mo n fi okun fa ọmọ kankan wọnu yara ki n to ma a ba wn laep.

Lasiko to n wo ẹlẹya ara rẹ lori Laptop
“Nigba ti iyawo ko ba mi gbe, bi wn ba wa sd mi, ara mi le dide nibi ti wn ti n ba mi ere, emi naa a si ba wn ere. Bi ba wo awọn fidio naa daadaa, yat sawn agbalagba yi, ko le ri mi pe gbogbo awn m yi ni mo b okoto bawn sun.

“Abule wa to wa ni Itsi-Toba nijba ibil deda ni iyawo mi wa, ko ba mi gbe. Emi kọ ni mo bi Tunrayọ, ọmọ ẹgbọn mi ni, emi si k ni mo e oyun fun Tunray, igba ti mo fẹẹ muu l kọ iṣẹ ni wn s pe ko le fi oyun kọ iṣẹ, mi o le s bo e e oyun naa. Mo maa n ba ere lẹẹkọọkan to ba rin si mi lara.

“Awn ọmọ ti wn ni mo n ba sun yi, kii e pe mo maa n fun wn lowo, ugbn igba min in ti wn ba wa sd mi, ogun naira, grun ati igba naira ni mo maa n fun wn, kii e gbogbo igba ni mo n fun wọn, awọn naa kii beere owo. Gbogbo aye lo ri i pe mi o loogun fm kankan ti wn fi n wa sd mi. Mi o ba iyawo adugbo sun, ita ni wn ti n wa, mi o si foogun pe wn.

“Emi k ni Bamidele bim fun, p loruk ẹni to fun Bamidele loyun, o si ti sal latigba to ti fun un loyun. Tori pe emi ni mo e ikom ọmọ naa lo j ki n s ni Temileyi, inu yara kan naa la j n gbe. m odi ti mo ba sun yi lo wa sile mi, igba to wa, o jun, igba to jun tan lo ba mi ere, ti ara mi si dide, mo gb pe mdun msan ni odi yi.

"Patapata ẹ, pẹlu nnkan ti mo ṣe yi, wn a s pe ki n l ṣẹwn, ugbn nnkan ti mo m daju ni pe mi o fipa mu awn m yi, funra wn ni wn n wa bami ere.”

Adajọ ile ẹjọ naa ti wa a paṣẹ pe kawọn ọlọpaa ṣi lọọ fi Peter ti wọn tun n pe ni Ọmọ Ọdẹ  si ọgba ẹwọn ijọba to wa ni Ọba digba ti igbẹjọ min in yoo waye.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI