AṢIRI IKU TO PA GBAJUMỌ OṢERE NNI, ADIO MAJESTER RE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, May 8, 2019

AṢIRI IKU TO PA GBAJUMỌ OṢERE NNI, ADIO MAJESTER RE O

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, ibanujẹ nla tun ti sọ lagboole awọn oṣere tiata bayii, pẹlu bi wọn ti ṣe padanu ọkan lara wọn, Ọgbẹni Gbọlahan Adio Majẹster.

Irọlẹ ana Tuside niroyin naa gba igboro kan nigba tawọn dọkita sọ pe akukọ ti kọ lẹyin ọkunrin naa.

AWIKONKO gbọ pe aisan kan ti wọn pe ni itọ ṣuga tawọn oloyinbo n pe ni Diabetes ni wọn loo ṣeku pa a, lẹyin ọpọlọpọ ọdun to ti n ba a finra.

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI