AWỌN ADIGUNJALE ṢA ỌLỌDẸ BAṢUBAṢU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, May 11, 2019

AWỌN ADIGUNJALE ṢA ỌLỌDẸ BAṢUBAṢU

Ori lo kọ baba agbalagba kan ti ko niṣẹ meji ju iṣẹ ọdẹ lọ yọ lọwọ iku ojiji. Bo tilẹ jẹ pe ọlọdẹ ko tii jẹ araaye, depodepo pe yoo jẹ ara ọrun titi dasiko ti ẹ n ka iroyin yi, sibẹ, ọwọ ti tẹ ọkan lara awọn adigunjale naa.

Ipinlẹ Delta lọhun niṣẹlẹ ibanujẹ naa ti waye lọsan ana Fraide.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI