Ẹ GBỌ, NIBO NI ṢỌLA WEIRD MC WA? - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, May 9, 2019

Ẹ GBỌ, NIBO NI ṢỌLA WEIRD MC WA?

Ẹ gbọ naa, njẹ ẹyin mọ ibi ti gbajumọ olorin takasufe nni, Adeṣọla Adeṣinbọ Idowu, tọpọ mọ si Weird MC wa?

Loootọ lọmọ bibi ipinlẹ Ogun naa tikọrin tipẹ, ṣugbọn ibeere tawọn to ti ri Ṣọla tipẹ lagboole orin ni wọn beere pe nibo lo wa. Ọṣu kẹjọ ọdun to kọja lawọn eeyan ti gburo rẹ gbẹyin.

Awo orin Ijoya lo sọ Ṣọla di ilu mọ ọn ka, paapaa bo tun ṣe bawọn Psquare kọrin papọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI