Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, gbogbo awọn ọmọ ẹgbẹ oṣere tiata patapata kaakiri agbaye ni wọn ti n fi atẹjiṣẹ ayẹyẹ ọjọ ibi ranṣẹ si ọkan lara awọn agba ọjẹ nidi iṣẹ naa, Oloye Mọnsuru Ijayegbemi.
Lati ọsẹ to kọja lawọn kan ti n ki i, to si jẹ pe lati aago mejila aarọ oni lawọn kan tun ti bẹrẹ si i fi mẹseeji loriṣiriṣi ranṣẹ si alaṣẹ ati oludailẹ ileeṣẹ Ariyọ Records ti wọn ti n ta oriṣiriṣi kasẹẹti niluu Abẹokuta ati agbegbe ẹ naa.
Ileeṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL naa n fi asiko yi ki ọkunrin naa pe igba ọdun, ọdun kan ni o.
No comments:
Post a Comment