FUNAAB: ẸGBẸ AKẸKỌỌ ṢAYẸYẸ ỌJỌ IBI FUN ỌGA AGBA, ỌJỌGBỌ KỌLAWỌLE SALAKỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, May 9, 2019

FUNAAB: ẸGBẸ AKẸKỌỌ ṢAYẸYẸ ỌJỌ IBI FUN ỌGA AGBA, ỌJỌGBỌ KỌLAWỌLE SALAKỌ

Ẹgbẹ awọn akẹkọọ nileewe fasiti Federal University of Agriculture, Abeokuta, FUNAABSU ti fi idunnu wọn han si ọga agba ileewe naa, Ọjọgbọn Kọlawọle Salakọ nipa ti ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mejidinlọgọta (58) to ṣe laipẹ yi.

Ọjọ kejidinlogun oṣu kerin to kọja yi layẹyẹ ọjọ ibi Ọjọgbọn Salakọ, ti gbogbo awọn oṣiṣẹ patapata si ba a ṣajọyọ, ṣugbọ ṣe lawọn adari ẹgbẹ akẹkọọ, SUG ya ọpọ eeyan lẹnu nigba ti wọn gbe fọto ọkunrin naa lọ kii ni ọfiisi ẹ.

Nigba to n dupẹ lọwọ awọn akẹkọọ naa, ti olori wọn, Adeọla Ahmed lewaju wọn lọ lo ti gbe oṣuba kare fun wọn pẹlu ipinu naa lati bu iyi fun un.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI