AKẸKỌỌ LAUTECH JẸ MILIỌNU MẸWAA NAIRA OWO TẸTẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, June 1, 2019

AKẸKỌỌ LAUTECH JẸ MILIỌNU MẸWAA NAIRA OWO TẸTẸ


Ṣe ni idunnu ṣubu lu ayọ ọdọmọkunrin akẹkọọ ile ẹkọ giga Ladoke Akintọla University of Technology (LAUTECH) to wa niluu Ogbomọṣọ, Ọpadeji Qudus ti wọn loo jẹ miliọnu mẹwaa owo tẹtẹ laipẹ yi.

Ẹka ikẹkọọ imọ-ẹrọ ni Qudus wa nile ẹkọ naa, ta a si gbọ pe aarin ọsẹ yi lo jẹ owo naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI