Bi ẹ ṣe n ka iroyin, ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede Naijiria tawọn ojẹ-wẹwẹ ti n gbaradi lati foju awọn alatako wọn, ẹgbẹ agbabọọlu Sẹnẹga gbolẹ baṣubaṣu lalẹ onii
Aago mẹfa aabọ ni idije naa yoo bẹrẹ ni Stadion Miejski Widzewa Łódź
Bo tilẹ jẹ gbogbo awọn ololufẹ awọn ẹgbẹ agbabọọlu mejeeji yi ni wọn ti n parọwa fun wọn pe ki wọn ri i daju pe wọn diju ja ija nla alẹ onii le yege si ipele to kan.
Yatọ si eyi, ẹgbẹ agbabọọlu Ukraine yoo wọ iya ija pẹlu ẹgbẹ agbabọọlu Panama nigba ti ẹgbẹ agbabọọlu Uruguay naa n gbaradi lati fiya jẹ Equador.
No comments:
Post a Comment