OGUN NLA DE N'ILE IGBIMỌ AṢOFIN ORILẸ-EDE NAIJIRIA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉSunday, June 9, 2019

OGUN NLA DE N'ILE IGBIMỌ AṢOFIN ORILẸ-EDE NAIJIRIA

Orin 'A ti t'oje bọ olooṣa lọwọ, o ku baba nla ẹni ti yoo bọ' lawọn aṣofin atawọn aṣoju-ṣofin orilẹ-ede yi n kọ bayii, latari ipo Aarẹ ile igbimọ aṣofin agba ati abẹnugọn ile igbimọ aṣoju-ṣofin to ṣi silẹ. Ibeere tawọn ọmọ Naijiria n beere lọwọ ara wọn bayii ni pe 'Tani ipo mejeeji yi yoo ja mọ lọwọ?'


No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI