PRIX DE DIANE LONGINES; ṢÉ ÒHUN NI ÀRÍYÁ ÌGBÈRÍKO TÓ GAJÙ LỌ, L'ÁGBÁYÉ? - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, June 13, 2019

PRIX DE DIANE LONGINES; ṢÉ ÒHUN NI ÀRÍYÁ ÌGBÈRÍKO TÓ GAJÙ LỌ, L'ÁGBÁYÉ?

Ohun tí àwon Europeans yááyì pipe ni àríyá tóní eré-ohun-ìgbáládùn prix de Diane Longines tilù Paris.

Séti eré idaraya niká so tàbí tí aso-tòhun-tisè-alaranbara tí wó n wò níbè?

Àyíká naa je ojú ní gbèsè, aso ara sìse pàtàkì bíi esin naa se jé.

Eré esin naa dàbi pé kòní ìgbá àbí àsìkò ni.

Eré esin náa kò túnwá dàbí ilé nla kan ràgbàdù bí àafin tó wà l'àyika náá tí wo n pè ní Grand Chateau.

Mo gbósùbà fún ògá ògo nígbà tí mo gánní ilé òhun. Ó tóbí, ó tún wá gùn.

Grand Chateau òhún ti wà láti 1600. Sùgbón wón ti wóo, won tún ti tún kó leyin ìgbà naa.

Eré elésin yen ni ìlà mèta tí o wo inú ara won. Ilè onígi loo yika. Sítandi nla kan sì wà níbè láti 1879.


Àayè náá tí n gba Prix du Jockey Club làlejò lati 1836 pèlú Prix de Diane  lati 1843.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI