BABA ADEBOYE ṢAYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌDUN MỌKANLELAADỌRIN IYAWO Ẹ LARA-ỌTỌ - IROYIN AWIKONKO

YÀJÓ-YÀJÓ
Sunday, July 14, 2019

BABA ADEBOYE ṢAYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌDUN MỌKANLELAADỌRIN IYAWO Ẹ LARA-ỌTỌ


Gbogbo awọn ọmọ Ridiimu, iyẹn The Redeemed Christian Church of God kaakiri agbaye ni wọn ti ba Pasitọ Folukẹ Adeboye yọ fun ti ayẹyẹ ọdun mọkanlelaadọrin (71) to ti lo loke eepẹ. 

Yatọ si pe gbogbo awọn ọmọ ijọ Ridiimu ba Mama Adeboye ti wọn tun n pe ni Mọmi G.O yọ, bẹẹ ni gbogbo awọn to n ri obinrin naa gẹgẹ bi awokọṣe ni wọn n ba a adupẹ lọwọ Ọlọrun fun anfaani ti wọpọ naa.


Baba Adeboye naa funra rẹ tun gba ikanni ayelujara ti Twitter lọ lati lọọ fi idunnu ẹ han, to si tun dupẹ lọwọ Ọlọrun fun iru obinrin bii ti mama naa to fi ta a lọrẹ.

Ohun kan ṣoṣo ti Pasitọ Enoch Adejare Adeboye tun sọ to n pa ọpọ awọn lẹrin ni bo tun ṣe sọ pe iyawo oun ko yatọ si boun ṣe pade lakọkọ, ko too di pe awọn fẹ ara wọn sile.77 retweets642 likes
  1. The Birthday Event Organized by the was one that really blew my mind. you are a indeed a mother.

  2. To My support system, My sweetheart, My one and only, It seems that everyone knows you turned a year older except me. In my eyes, you are exactly the way that you were when I met you for the first time – stunning and gorgeous. Happy Birthday aya mi @pastorfoluadeboye
  3. You can send your birthday wishes for to . God bless you !

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI