Ẹ WO AGUNBANIRỌ TI KO NI APA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Thursday, July 4, 2019

Ẹ WO AGUNBANIRỌ TI KO NI APA

Ọrọ kan to n lọ kaakiri ikaani ayelujara lasiko yi ni ti ọdọmọbinrin agunbanirọ kan ti ko ni apa ọwọ, to si n ya awọn eeyan lẹnu nipa bo ṣe gba ile-ẹkọ kọja , to fi de ipele agunbanirọ.

Bo tilẹ jẹ pe kii ṣe bi wọn bi agunbanirọ naa niyẹn, ṣugbọn lojiji lo padanu ọwọ ẹ mejeeji sinu ijamba kan lọdun diẹ sẹyin, to si pinu pe oun yoo kẹkọọ gboye lai nii wo ti ipenija to wa lara oun.

Titi dasiko ta a fi ko iroyin yi jọ la ko tii mọ orukọ agunbanirọ naa.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI