ỌMỌTỌLA JỌLADE ṢAYẸYẸ IKẸKỌỌGBOYE ỌMỌ Ẹ NILUU OYINBO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Thursday, July 4, 2019

ỌMỌTỌLA JỌLADE ṢAYẸYẸ IKẸKỌỌGBOYE ỌMỌ Ẹ NILUU OYINBO

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, inu idunnu ati ayọ ni gbajugba oṣere tiata nni, Ọmọtọla Jolade Ẹkẹinde wa bayii pẹluu bi ọmọ ẹ Michael ṣe kẹkọọ gboye ni fasiti Eastern Mediterranean to wa ni Cyprus.

Omotola jalade Ekeinde son graduates 
Ori ikanni ayelujara Instagram ni gbajugbaja nna gbe fọto naa si, nibi to ti n jẹ kawọn eeyan mọ pe ọmọ oun ti kẹkọọ gboye, ki wọn ki oun ku oriire.

 Omotola jalade Ekeinde son graduates


Omotola jalade Ekeinde son graduates

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI