Fọnran kan to n lọ kaakiri ori ayelujara bayii, ko da a, tawọn eeyan ṣi n sọrọ lori ẹ dasiko yi ni ti iyaale ile kan toun atawọn ọmọ rẹ n sun sẹgbẹ opopona, paapaa ni papakọ ofurufu Naijiria to wa niluu Berlin, Germany.
Ohun ta a gbọ ni pe ilu Munich ni obinrin naa ti wa ni Berlin lati gba iwe irinna ẹ tuntun, eyi ti ọjọ ti lọ lori ẹ.
Wọn ni nigba ti wọn ko tete da wọn lohun, ti ko si sibi ti wọn fẹ ẹ lọ, lo mu ki wọn maa sun kaakiri ẹgbẹ opopona.
Eyi lohun tawọn eeyan n sọ nipa ẹ:
No comments:
Post a Comment