LIZ ANJỌRIN, GBAJUMỌ OṢERE TIATA PARI ILE OLOWO NLA SILUU EKO - IROYIN AWIKONKO

YÀJÓ-YÀJÓ
Friday, July 12, 2019

LIZ ANJỌRIN, GBAJUMỌ OṢERE TIATA PARI ILE OLOWO NLA SILUU EKO

Bo tilẹ jẹ pe iyalẹnu lọrọ gbajumọ oṣere tiata nni, Liz Anjọrin ṣi n jẹ fun ọpọ awọn eeyan, paapaa awọn oṣere ẹgbẹ rẹ lori ile olowo nla tuntun to ṣẹṣẹ pari sagbegbe ijọba ibilẹ Eti-Ọsa niluu Ekoo, bẹẹ awọn eeyan lo n ki ku oriire.

Bẹ o ba gbagbe, lọdun to kọja ni Liz Anjọrin ra mọto olowo nla kan, to si ni kawọn eeyan ṣi maa reti nnkan nla min in , tori pe iyẹn naa yoo tun ya wọn lẹnu, to si jẹ pe loootọ, nigba to gbe ẹri naa sori ayelujara rẹ, agba iyanu lo jẹ.

Liz Anjorin shows off her new house 

1 comment:PÍN-IN KÁÀKIRI