SUPER EAGLES JIYA NLA LỌWỌ ALGERIA - IROYIN AWIKONKO

YÀJÓ-YÀJÓ
Sunday, July 14, 2019

SUPER EAGLES JIYA NLA LỌWỌ ALGERIA

Iyalẹnu lọrọ goolu ti Algeria fi pari ifigagbaga to ku ki wọn fi wọ aṣekagba ninu idije AFCON to n lọ lọwọ lorilẹede Egypt.

Aami ayo meji si ẹyọkan ni ikọ Algeria fi doju ikọ Naijiria bolẹ lalẹ onii, to si mu ki gbogbo ọmọ Naijiria kawọ mọri maa sunkun ipadanu nla naa.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI