MO PARIWO TO FUN UN YIN NIPA BUHARI - FAYỌṢE TUN JU BỌMBU ỌRỌ SITA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, July 15, 2019

MO PARIWO TO FUN UN YIN NIPA BUHARI - FAYỌṢE TUN JU BỌMBU ỌRỌ SITA

Gomina ana nipinlẹ Ekiti, Peter Ayọdele Fayọṣe tun ti ju bọmbu ọrọ gẹgẹ bo ṣe maa n juu nipa Aarẹ orilẹede yi, Ọgagun Muhammadu Buhari, to si loun pariwo titi fawọn ọmọ Naijiria p ki wọn ma ṣe dibo fun un.

Ori ikanni ayelujara ni Ayọdele Fayọṣe ti sọrọ naa nigba to n ba Alagba Reuben Fasoranti kẹdun iku ọmọ ẹ, Arabinrin Funkẹ Ọlakunrin tawọn agbebọn kan pa danu nipinlẹ Ondo lọjọ Ẹti ọsẹ to kọja.

O sọ pe ki Ọlọrun gba awọn ọmọ Naijiria ninu ijọba "Next Level" to jẹ ti ipaniyan, ijiniyan, airiṣẹ ṣe, iṣẹ, iwa ko-kan-mi ati ọrọ aje to n wọmi, to si ni oun ke to pe ki wọn ma ṣe tẹle ọrọ Buhari.


  1. Nigerians, may God save us in this "Next Level" of Killings, Kidnappings, Joblessness, Poverty, Cluelessness and Recession...Fasten your Seat Belts. Remember I warned against Sai Buhari! Mo ke to o! Baba Fasoranti, I sympathise with you and other Nigerians. God will console you.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI