HAUSA ATI YORUBA KỌJU IJA SIRA WỌN L'EKOO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 19, 2019

HAUSA ATI YORUBA KỌJU IJA SIRA WỌN L'EKOO

Ṣe lọrọ di boolọ o yago lọjọ Aiku, Sande ana nigba ti wọn lawọn Hausa ati Yoruba kọju ija sira wọn, ti wọn bẹrẹ sii ṣe ara wọn baṣubaṣu, ko da, ti ọpọ dukia ṣofo danu, tawọn eeyan si farapa yannayanna.

Agbegbe ọja nla kan to wa ni Oke-Odo nipinlẹ Eko, loju ọna Ekoo si Abẹokuta nija nla naa ti waye, to si jẹ pe fun bi i wakati mẹrin lagbegbe naa fi pa lọọlọ.

Diẹ re e lara awọn fọto iṣẹlẹ naa. 
 Image result for Tension as Yoruba, Hausa clash in Lagos market

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI