IYAALE ILE JU ỌMỌ OOJỌ SINU ṢALANGA - IROYIN AWIKONKO

YAJO-YAJO

Monday, August 19, 2019

IYAALE ILE JU ỌMỌ OOJỌ SINU ṢALANGA

Epe nla-nla lawọn eeyan n gbe iyaale ile kan ṣe, lori bi wọn ṣe loo ju ọmọ to ṣẹṣẹ bi sinu ṣalanga, ṣugbọn tawọn araadugbo naa tete yọ ọmọ naa jade, ko too ku.
No comments:

Post a Comment

PIN-IN KAAKIRI