O MA ṢE O, ỌLAJUMỌKẸ DI AWATI N'ILỌRIN - IROYIN AWIKONKO

YAJO-YAJO
Sunday, September 8, 2019

O MA ṢE O, ỌLAJUMỌKẸ DI AWATI N'ILỌRIN

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara niluu Ilọrin ti kede sita pe awọn n wa ọdọmọbinrin ẹni ọdun mọkandinlogun kan, Sa'adat Ọlajumọkẹ Bakare ti wọn lawọn obi ẹ ko ri lati ọjọ Aje Mọnde ọsẹ to kọja yi, iyẹn ọjọ keji oṣu ti a wa yi.

 
Akẹkọọ fasiti ipinlẹ Kwara tiluu ilọrin, iyẹn University of Ilorin la gbọ pe Ọlajumọkẹ wa ni ẹka ikẹkọọ iṣẹ ile ati ounjẹ igbalode ti Oloyinbo n pe ni Home Economics and Food Science Department.

 
Fun ẹnikẹni to ba kofiri Ọlajumọkẹ, awọn nọmba yi ni ki ẹ pe 08062623867 or 08056678859

No comments:

Post a CommentPIN-IN KAAKIRI