BABA ÌJẸ̀BÚ DI ODOLE TILUU ILE IFẸ̀, GBENGA ÀTÀWỌN ÈÈYÀN JANKAN-JANKAN LO WÁ NIBẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Saturday, October 19, 2019

BABA ÌJẸ̀BÚ DI ODOLE TILUU ILE IFẸ̀, GBENGA ÀTÀWỌN ÈÈYÀN JANKAN-JANKAN LO WÁ NIBẸ

Gbajugbaja oníṣòwò nnì, Oloye Kesington Adebutu ni wọn ti yàn gẹ́gẹ́ bí Odole tiluu Ilé Ifẹ̀ báyìí, latari àwọn ipa àti idagbasoke manigbagbe tó ń kó lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, pàápàá niluu Ilé-Ifẹ̀. 


Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ogun, Ọtunba Gbenga Daniel to jẹ Fẹsọjaye Ilé Ifẹ̀ àtàwọn ọtọkulu láwùjọ ni wọn kò gbẹyin níbi eto ìfinijoyè tó ń lọ lọ́wọ́ títí dasiko tá a kọ ìròyìn yí tán. 


Díẹ̀ re lára àwọn fọ́tò bí eto naa ṣe ń lọ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI