Ẹ WO ỌKÙNRIN TÓ ṢE ÌGBÉYÀWÓ PẸLU OBINRIN MÉJÌ LỌ́JỌ́ KAN ṢOṢO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, November 19, 2019

Ẹ WO ỌKÙNRIN TÓ ṢE ÌGBÉYÀWÓ PẸLU OBINRIN MÉJÌ LỌ́JỌ́ KAN ṢOṢO


A kò rí irú èyí rí lọrọ kayeefi tó ń tẹnu ọpọ̀ èèyàn jáde lópin ọ̀sẹ̀ tó kọjá yí nígbà tí wọn rí àwòrán ọkùnrin kan tó ṣègbéyàwó pẹluu obìnrin méjì lọ́jọ́ kan ṣoṣo.


Shadrack ni wọn pé ọkùnrin ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà náà, tí wọn loo fitan tuntun balẹ láti ṣe ohun tẹnikẹni kò lérò wípé ó lè ṣẹlẹ̀. 


Agbegbe kan tí wọn pé ní Uzere tó wà nijọba ibile Isoko South, ipinlẹ Delta ni wọn lẹtọ ìgbéyàwó náà tí wáyé. 

Fawọn ti ko bá mọ, ọ̀sẹ̀ mélòó kan sẹ́yìn là gbọ́ pé ọkùnrin kan náà fẹ obìnrin mẹta lẹẹkan ṣoṣo lorilẹ-ede Ghana, ìyẹn là gbọ́ pé ó sì ń jà nilẹ kí eleyi náà tóó wọlé de. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI