MERCY JOHNSON GBE FỌTO AWOṢIFILA MỌLẸBI RẸ SITA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


https://haxbyq.com/mario?h=waWQiOjExNDYwMDIsInNpZCI6MTE4NDA4MCwid2lkIjo0MjE1NzYsInNyYyI6Mn0=eyJ&si1=&si2=


Monday, December 2, 2019

MERCY JOHNSON GBE FỌTO AWOṢIFILA MỌLẸBI RẸ SITA

Ọpọ awọn ti wọn ri fọto gbajumọ oṣerebinrin tiata oloyinbo nni, Mercy Johnson Okojie atawọn mọlẹbi rẹ ni wọn n kan saara sii wipe o lo ara rẹ daadaa lẹyin ọmọ mẹta.
 
Ninu fọto naa la ti ri Mercy Johnson Okojie funra rẹ; Ọkọ rẹ, Ọmọba Odi Okojie atawọn ọmọ wọn, Purity, Henry ati Angel Okojie.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI