EYI NI B'AWỌN BOKO HARAM TUN ṢE F'ỌPỌ EMI S'OFO DANU NI BORNO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉTuesday, February 11, 2020

EYI NI B'AWỌN BOKO HARAM TUN ṢE F'ỌPỌ EMI S'OFO DANU NI BORNO

Alẹ ọjọ Aiku Sannde ijẹta yii ti i ṣe ojo kesan-an, oṣu keji ta a wa yii ni awọn ẹgbẹ afẹmiṣofo nni, Boko Haram ya wọ inu ilu Auno to wa n'ipinlẹ Borno, ti wọn si pa eeyan ti ko din ni ọgbọn ninu ilu naa danu.

Image may contain: sky, outdoor and nature 
Yatọ si eyii, wọn tun dana sun mọto ti ko din ni ogun.

Image may contain: outdoor 
AWIKONKO gbọ pe, wọn tun ji ọpọ awọn obinrin at'awọn ọmọde gbe, bẹẹ ni wọn si ti fẹẹ sọ ilu naa d'ahoro.

No photo description available. 
Ni kete t'iṣẹlẹ naa ti waye ni Gomina ipinlẹ Borno, Gomina Babagana Zulum ti lọ sibẹ lati lọọ wo bi ikọlu naa ṣe ri i. 

Image may contain: 5 people, people standing and outdoor

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI