VICTOR LU JIBITI BILIỌNU MẸSAN-AN NAIRA L’ABẸOKUTA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, February 8, 2020

VICTOR LU JIBITI BILIỌNU MẸSAN-AN NAIRA L’ABẸOKUTA

Ko si ọrọ meji to n ja rain-rain nil kaakiri orilẹ-ede Naijiria lasiko yii bi ko e ti dmkunrin kan ti wn lo o lu awn eeyan to to gbrun mwaa ni jibiti owo ti ko din ni bilinu msan an (N9b) naira, ti wn si lo n gbero lati na papa bora plu owo olowo.

s to kja yii la gb pe airi dmkunrin naa ti wn pe oruk rẹ ni Nwabuba Victor Ifeanyi, ti wn ni ka ikkọọ Chemistry lo wa ni fasiti ti wn ti n k nipa iṣẹ agb ati gbin, iyn FUNAAB n’ilu Abokuta, ati pe ipele to gbyin, iyn 400level lo wa tu s’awn eeyan l’ọwọ l’asiko ti wọn lo n di ru rẹ lati salọ s’ilu Dubai ni orilẹ-ede Egypt.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni ọdun to kọja ni Victor bẹrẹ ifowo-dokoowo ori ayelujara ti wọn n pe ni Forex Trading, ti wọn si l’awọn to lowo lowo daadaa ni wọn n fowo si i lati d’okoowo pẹlu e.

A gbọ pe ida ogun (20%) ni Victor maa n fun awọn to ba k’owo si ileese rẹ lori ayelujara to pe ni Vickson Enterprise l’eyin ọsẹ meji, ti inu wọn yoo si dun un. Eyi gan an ni wọn lo o jẹ k’awọn to mo eto yii bẹrẹ si i pe awọn ọrẹ rẹ at’awọn ebi wọn lati fi owo wọn si i, k’awọn naa le jẹ ninu anfaani naa.

Wọn ni awọn bi ojogbọn, oluko, akekoo at’awọn eeyan n’ile eko fasiti FUNAAB ati jakejado ni wọn ko owo si i, ti wọn si n gba owo naa bo ṣe ye, ti a si gbọ pe awọn ti ko din ni egberun mewaa eeyan ni wọn n f’owo wọn d’okoowo pẹlu Victor.

Ṣe ni wọn ni nnkan ko lo gẹgẹ bo ṣe ye ko lo ni nnkan bi ọsẹ meta s’eyin, ti wọn si l’awọn to n f’owo d’okoowo ko ri owo gba mo, ti wọn si l’awọn eeyan bẹrẹ si i beere l’ọwọ ara wọn pe ki lo le sele, sugbọn ti wọn ko r’ni da wọn lohun.

Gbogbọ igba la gbọ pe wọn maa n pe Victor lori foonu lati beere idi ti ko fi san owo olowo, ti a si tun gbọ pe ṣe l’awọn ti wọn gbiyanju lati fi opin si okoowo naa ko ri owo wọn gba pada.

Wọn ni n’igba t’awọn eeyan ko gburo Victor lo jẹ ki wọn gbera lọ ọ ba a n’ile l’j Wesidee ọsẹ to kọja yii, ti wọn si ri i pe o ti di gbọgbọ ru rẹ lati na papa bora, eyi lo mu ki wọn bẹrẹ si i f’inibu luu, ti wọn si wo o lo teṣan ọlọpaa to wa ni Eleweran lati fi to ga ọlọpaa leti.

AWIKONKO gbọ pe Victor ti pari idanwo aekagba rẹ, ti wọn si lo n duro lati pari idanrawo, iyn Project , ugbọn ti wọn ni gbọgbọ erongba rẹ ni lati fi owo rin in, ko le ri owo olowo gbe salọ lo n wa.

Gbogbo akitiyan lati ba Abimbla Oyeymi sr lori iṣẹl naa lo ja si pabo titi d’asiko ta a ’akojp iroyin yii tan.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI