Wọn ní bí okete bá dàgbà, ọmú ìyá rẹ ni yóò mú. Wọn yí gan án lọrọ tó lọ nibamu pẹ̀lú bí ọdọmọbinrin àgbabọọlu nnì, Francisca Ordega ṣe kọ ilé awoṣifila fún màmá rẹ.
Ayajọ ọjọ àwọn Mama tó wáyé káàkiri àgbáyé ni Francisca tí fún màmá rẹ yìí láti fi mọ rírí ipa tó ko láyé ẹ.
No comments:
Post a Comment