IJỌBA NÀÌJÍRÍÀ FẸẸ WỌGILE IPEJỌPỌ RẸPẸTẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Tuesday, March 17, 2020

IJỌBA NÀÌJÍRÍÀ FẸẸ WỌGILE IPEJỌPỌ RẸPẸTẸ


Ile igbimọ aṣofin kekere n'ilu Abuja ti bẹrẹ igbesẹ lati wọgile ipejọpọ rẹpẹtẹ kaakiri orilẹ-ede Nàìjíríà. 

Òní ni ọkàn lára àwọn ọmọ ile igbimọ aṣofin, Ọnọrebu Luke Onofiok lo daba náà pẹ̀lú erongba láti fi dẹkùn itankalẹ àárín Coronavirus.

Bẹ́ẹ̀ ni wọn tún pe ijọba apapọ láti fagile idije gbogboogbo, ìyẹn National Sports Festival.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI