ÌJÀ PARI! ỌṢIỌMỌLẸ, AJIMỌBI PARI ÌJÀ L'ỌDỌ BUHARI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, March 20, 2020

ÌJÀ PARI! ỌṢIỌMỌLẸ, AJIMỌBI PARI ÌJÀ L'ỌDỌ BUHARI


'Ija d'opin, ogun sì se' lorin tí gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC l'órílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kọ lónìí nígbà tí wọn rí alaga ẹgbẹ́ náà lapapọ, Adams Ọṣiọmọlẹ àti igbakeji alaga ni ẹkún ìwọ-oòrùn, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi ni ile agbára n'ilu Abuja, ìyẹn lọdọ Ààrẹ Muhammadu Buhari.


Agbẹnusọ Buhari, Ọgbẹni Fẹmi Adeṣina lo gbé fọto náà sórí ìkànnì ayélujára tí fesibuuku laipẹ yìí. 


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI