O PARI! ILE ẸJỌ LE ỌṢIỌMỌLẸ, ALAGA ẸGBẸ OṢELU APC DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, March 4, 2020

O PARI! ILE ẸJỌ LE ỌṢIỌMỌLẸ, ALAGA ẸGBẸ OṢELU APC DANU

Lonii Ọjọru ti i ṣe Wẹside ni ile-ẹjọ giga to f'ikalẹ silu Abuja paṣẹ wi pe ki alaga ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, Kọmureedi Adams Ọṣiọmọlẹ lọ ọ jokoo sile fungba diẹ.

Onidajọ Danlami Senchin lo gbe idajọ naa kalẹ lori b'awọn ọmọ ẹgbẹ naa ṣe f'ẹsun kan an wi pe oun lo n fa wahala to n ṣe ṣẹlẹ ninu ẹgbẹ naa kaakiri orilẹ-ede Naijiria, ti wọn si tun sọ pe ko yẹ lẹni to n jẹ adari kankan.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI