AYAJỌ ÀWỌN ỌMỌDÉ! GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ ṢÈLÉRÍ Ẹ̀KỌ́ ÌGBÀLÓDÉ FÁWỌN ỌMỌDÉ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, May 27, 2020

AYAJỌ ÀWỌN ỌMỌDÉ! GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ ṢÈLÉRÍ Ẹ̀KỌ́ ÌGBÀLÓDÉ FÁWỌN ỌMỌDÉ


Lónìí Wẹside, ọjọ́ kẹtàdínlọgbọ̀n ni ayajọ àwọn ọjẹ wẹ́wẹ́, ìyẹn àwọn ọmọdé. Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq tí ṣèlérí wí pé kò sí ọmọdé kan táwọn yóò tanu, àti pé gbogbo wọn pátápátá ní wón yóò jẹ nínú ètò òṣèlú awaarawa tó wà níta. 

Gomina AbdulRazaq sọ pé nípa àwọn ìlànà eto tó wà nílẹ̀ nínú ìjọba yìí, eto ńlá lo tí wá nilẹ fún gbogbo àwọn ọmọdé, pàápàá àwọn akẹ́kọ̀ọ́, tó sì ni gbogbo wọn ni yóò bẹ̀rẹ̀ sii gba idanilẹkọọ lọ́nà ìgbàlódé. 

Ó jẹ kò di mimọ pé kò níí sì ọmọdé kan tijọba òun yóò tá dànù, tàbí wí pé kẹnikẹni fi ẹtọ wọn dùn wọn, bẹẹ lo ni gbogbo wọn ni yóò láǹfààní láti figagbaga pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ wọn káàkiri àgbáyé. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI